Our ServicesNews From The BBC

A Yoruba Perspective


Òwe Yorùbá: Mélòó lo lè parí nínú òwe Yorùbá yìí?
Fi ìdáhùn tó yẹ sí àwọn òwe wọnyii lórí ìkànnì BBC Yorùbá.

Idowu Olakunrin: Kò sí ẹni tó lé è dí àlàfo tí Funke fi sílẹ̀
Ọkọ olóògbé Olufunke Olakunri bú sí ẹkún lásìkò tó ń se ìdárò ìyàwó rẹ̀ tí àwọn agbébọn pa ní ìpínlẹ̀ Ondo.

Ayinla Kollington: Ìyàwó mí títí láéláé ni Salawa Abẹni
Alhaji Kollington Ayinla tun sọ fun BBC Yoruba pe orogun owo lasan ni ìjà oun ati Barrister, awọn si dijọ bẹrẹ orin Fuji ni.

Ìsẹ̀lẹ̀ jákèjádò orílẹ̀èdè àgbáyé láàárín ìṣẹ́jú kan
Àkójọpọ̀ ìsẹ̀lẹ̀ jákèjádò àgbáyé láàárín ìṣẹ́jú kan lórí BBC.

RUGA: Gómìnà ìpínlẹ̀ Kano ní gbogbo Fulani lè máà bọ̀ lọ́dọ̀ àwọn
Bí ẹgbẹ́ àwọn àgbà ẹkùn àríwá ṣe ń ké sí àwọn Fulani Darandaran pé ọmọ padà wálé, àwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ Yorúbá náà ní kí wọ́n má bẹ̀rù.

BBC Yoruba: Àwọn ìròyìn tó tayọ lọ́sẹ̀ yìí
Nínú gbogbo ìròyìn tí a mú wá fún yín láàrín ọ̀sẹ̀ yìí, àwọn wọ̀nyìí ló jẹ́ kàbìtì kàbìtì tí ẹ ò ní fẹ́ gbàgbé.

Ruga: Ọ̀pọ̀ àwọn ìpínlẹ̀ tó ń fẹ́ Ruga ló wá láti apá òkè ọya
Amọ agbẹnusọ fun aarẹ Muhammadu Buhari ti kede pe agbekalẹ abule Ruga yoo mu imọtoto ba ẹran ta n jẹ.

Yinka Ayefele, ìdí tí ó fí ní òun kò bí ìbẹta lọ́jọ́sí
Ni oṣu diẹ sẹyin iroyin jade pe Yinka Ayefẹlẹ bi ibẹta, gbajugbaja olorin naa niyi ninu alaye rẹ pẹlu BBC News Yoruba lori idi ti ko fi kede ibi awọn ọmọ rẹ nigba naa.

Olakunrin murder: Ọlọ́pàá ní OPC kò láṣẹ láti fipa lé ẹ̀yà kan nílẹ̀ Yorùbá
Ẹgbẹ́ OPC ní ìkùnà láti tú àṣírí àwọn tó pa Funke Olakunrin yóò fa ìgbésẹ̀ láti ọ̀dọ̀ àwọn.

Africa in Pictures: Àwọn àwòràn tó ṣàrà ọ̀tọ̀ láti ilẹ̀ Afirika
Awọn aworan yii lo n se afihan ọp isẹlẹ to waye laarin ọsẹ to n pari yii lati awọn orilẹede yika ilẹ Afirika.

Ìtàn Mánigbàgbé: Ọ̀rẹ́ àjèjì ló kóbá Afọnja, tí Ilọrin fi bọ́ lọ́wọ́ Yorùbá
Eyi ni itan igbe aye Aarẹ Ọna Kakanfo Afọnja tilu Ilọrin, ẹni to fi inu wenu pẹlu Fulani, amọ to jẹ iwọ.

FaceApp: Ǹjẹ́ ẹwu wà nínú lílò ẹ̀rọ yìí?
Oju opo Instagram ti kun pitimu bayii fun fọto awọn oṣere tiata, ti wọn parada di arugbo, eyi to n sọ bi wọn yoo se ri lọjọ ogbo wọn.

AFCON 2019 final: Kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ Algeria là kìnìún Senegal mọ́ lẹ̀ lẹ́ẹ̀kejì gba ife
Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Algeria ló gba ife ẹ̀yẹ ìdíje AFCON 2019 lẹ́yìn tí wọ́n ṣíná ìyà fún Senegal nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ àṣekágba ìdíje ọ̀hún.

Pinnick: Danny Jordaan láti South Africa ló rọ́pò rẹ̀
Ajọ to n mojuto bọọlu gbigba ni Afrika ti juwe ile fun Amaju Pinnick, wọn si ti rọpo rẹ.

Mikel Obi: Orílẹ̀èdè Egypt ni mo ti bẹ̀rẹ̀ ayò, ibẹ̀ náà ló parí sí
Lẹ́yìn ọ̀pọ̀ ọdún tí ó ti ṣojú Nàìjíríà nínú eré bọ́ọ̀lù, balógun Super Eagles, John Obi Mikel ti kéde ìfẹ̀hìntì fún Nàìjíríà.

TUNNGR: Ta ló ṣe móríyá fún ọ jù lọ ní Super Eagles?
Ọ̀pọ̀ ènìyàn ló ti ń fi ẹni tó se móríyá fún wọn jù lọ ní ìdíje erébọ́ọ̀lù ilẹ̀ Afirika, Afcon 2019 hàn.

#TUNNGR: Ẹyẹ j’ẹyẹ lọ! Super Eagles f'ìyẹ́ bo Carthage Eagles Tunisia mọ́ 'lẹ̀
Ẹgbẹ agbábọọlù Nàìjíríà ti gba ipò kẹta(Golden Bronze) nínú ìdíje AFCON 2019 lẹyìn tí wọn to ẹgba sí Tunisia nídìí.

AFCON 2019: Ki akọnimọọgba Naijira bá wọn sọ̀rọ̀ kóríyá
Àwọn ọmọ Naijiria gba Rohr nímọ̀ràn pé kó mójútó àwọn agbabọọlu adi-ẹ̀yìn-mú wa àti amúlé wa kí Naijiria lè borí.

Lafup: Kò sí ẹni kankan tó ń ṣe ẹ̀fẹ̀ ní Ibadan nígbà táwa bẹ̀rẹ̀
Oluwasegun Ogundipe ní ìwúrí pé òun ni wọ́n ń pè ní Ọba ẹ̀fẹ̀ ti ìlú Ibadan báyìí.

Nike Davies-Okundaye: Àṣírí tó wà nídìí ìmúra mi
Gbajúgbajà ni Nike Davies-Okundaye pẹ̀lú gèlè ńlá bíi igi àràbà tó máà ń fi ṣe ìdánimọ̀ ara rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi ayàwòrán.

Funke Akindele jẹ àkàndá ẹ̀dá - Adaku
Omotunde Adebowale, ogbontarigi òṣèré ti ayé mọ̀ sí Adákú nínú eré Jẹnifa sọ̀rọ̀ kíkún lórí ìkọraẹnisílẹ̀ láàrin lọ́kọláya fún BBC.

Ti o bá dá ara ẹ lójú, ki ẹni tó n ṣe irun kí n gbọ́?
Ìgbéga Àṣà àti ìṣe Yorùbá ló jẹ́ BBC Yorùbá lógún pé ki ó má parun, èyí ló mú wa jáde lọ bèèrè ìkíni fáwọn onídìrí.

Iṣẹ́ ìdọ̀tí ni ẹran títá, ṣùgbọ́n nínú ẹ̀gbin lowó wà - Derin Ẹlẹran
Aderinsola Taiwo bá BBC Yorùbá sọ̀rọ̀ lórí erè tó wà níṣẹ́ alápatà ti ó yàn láàyò lẹ́yìn ti ó fiṣẹ́ ile ìfowópamọ́sí sílẹ̀

Fasoranti: Dẹ́rẹ́bà tó wa ọmọ Fasoranti ṣàlàyé bí wọ́n ṣe pa Funke Olakunrin
Dérébà tó wa ọkọ ti wọ́n ti pa Funke Olakunrin, ọmọ bàbá Fasoranti lopopona marosẹ ilu Ọrẹ lọjọ Ẹti ti bá BBC sọ̀rọ̀ lórí ohun ti ojú rẹ rí.

Olólùfẹ́ méjì jábọ́ láti àjà kẹsàn án lásìkò tí wọ́n n ṣe kerewà
Igbagbọ awọn ọlọpaa ni pe niṣe ni awọn ololufẹ naa n ba ara wọn lopọ lori ferese naa nigba ti wọn jabọ.

Fasoranti: Ẹ̀mí àwọ̀n darandaran Fulani kò dè mọ́ ní Gúsù Nàìjíríà, kí wọ́n padà sókè ọya ní kíákíá
Ẹgbẹ àgbà òkè ọya Nàìjíríà, NEF ni ọrọ̀ ìdúnkooko tó n wáyé lẹnu àwọn àgbà ìhà Guusu Naijiria ló ń mú kí àṣẹ náà wáyé

Oluwo: Inú ìwé kíkà ni ọja ọ̀la àwọn Fulani wà
Oluwo ni aisi ẹkọ iwe lo n se okunfa iwa jagidi-jagan amọ eto ẹkọ to ye kooro lo le wa ojutu laelae si isoro naa.

Face app: Àwọn òṣèré tíátà kan ṣàfihàn fọ́tò ọjọ́ ogbó wọn
Oju opo Instagram ti kun pitimu bayii fun fọto awọn oṣere tiata, ti wọn parada di arugbo, eyi to n sọ bi wọn yoo se ri lọjọ ogbo wọn.

RUGA: Gbogbo ọmọ Nàìjíríà ló lásẹ láti gbé ìlú tó bá wù ú - Buhari
Àjọ Northern Elders Forum (NEF) láìpé yìí késí àwọn darandaran Fulani kí wọ́n padà sókè ọya ní kíákíá.

COZA: Lẹ́yìn ìwadìí PFN ni CAN tó leè sọ̀rọ̀ lórí ẹ̀sùn tí wọ́n fi kan Fatoyinbo
Ẹgbẹ ọmọlẹtin Kristi, CAN, ni oun ko mọ nipa awọn ọmọ ẹgbẹ naa to lọ si ileejọsin Biọdun Fatoyinbo.

Dino Melaye: Ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá yóò ṣèwádìí fídíò tí Dino ti ń náwó fún olórin kan
Ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá ti sọ pé àwọn yóò ṣèwádìí fídíò tó lu ayélujára pa níbi tí Sẹ́nẹ́tọ̀ Dino Melaye ti ń ná olórin lówó.

Kàn sí BBC Yorùbá
Ẹ kàn sí ojú òpó ìròyìn BBC Yorùbá.

Local Housing

This is one of the main issues facing local people. The inadequacy of social housing stock continues to be the main concerns of local people. And it is getting worst.

Read More

Drugs And Illegal Substances

Taking illegal drug is always fraught with danger. You don't need me to tell you that - your grand mother will say the same. The high very often tend to perpetual low that you will never get out from. Get advise now before it is too late

Read More

Knife Attacks

Who goes around with a knive as weapon of protection is deluded. It will inevitably be your comeuppance. Just in case you do not understand, it will kill you. There is no justification for carrying a knive excerpt when you are foraging in the jungle.

Read More

Gang Culture

We were all young once - doing things adults will frown upon. This was at school or in the play grounds. But as we grew up, people we wanted to associate with start to shrink in numbers as our brain matured correspondingly and as a result doing the right thing. Pick your friends judiciously.

Read More

Local Parks

From a personal experience - the local park is a refuge for meditation,physical exploration and mental rejuvination. Just go for a slow run and see how you feel afterwards. Physical and mentally rewarding. Don't just take my words for it - it is a scientific fact. Please do try it.

Read More

24/7 Support

We are your one stop local solution advocate. Dont't carry all that weight on your own we are here to not only relief some of it, but to help you get back to you again.

Read More
Established since 2000

We Are Ready To Assist